ọsàn
Language Family | Variety Group | Variety | Words |
---|---|---|---|
Proto-Itsekiri-SEY | Southeast Yoruba | Ìjẹ̀bú | erèm̀bó |
Ìkálẹ̀ | - | ||
Ìlàjẹ | - | ||
Oǹdó | àlùmọ́yẹ̀n | ||
Ọ̀wọ̀ | - | ||
Usẹn | àlìmóyì | ||
Proto-Yoruba | Central Yoruba | Èkìtì | ọsọ̀n gụ̀dụ̀gbá, òròǹbó |
Ifẹ̀ | - | ||
Ìgbómìnà | - | ||
Ìjẹ̀ṣà | - | ||
Western Àkókó | |||
Northwest Yoruba | Àwórì | ọsàn | |
Ẹ̀gbá | - | ||
Ìbàdàn | ọsàn | ||
Òǹkò | ọsàn | ||
Ọ̀yọ́ | ọsàn | ||
Standard Yorùbá | ọsàn, òrom̀bó | ||
Northeast Yoruba/Okun | Ìbùnú | ìlèmù | |
Ìjùmú | ìlèmù | ||
Ìyàgbà | ìlèmù | ||
Owé | ìlèmù | ||
Ọ̀wọ̀rọ̀ | àlèmù |
Proposed to be derived from Proto-Yoruboid *ɔ̀-sã́, possibly from ọ̀- (“nominalizing prefix”) + sán (“to shine powerfully, to strike, to be powerful”). Cognate with Igala ọ̀rọ́ka, Itsekiri ọ̀sọ́n.
ọ̀sán
From ọ- (“nominalising prefix”) + sán (“to tie”).
ọsán