Hello, you have come here looking for the meaning of the word User:Egbingíga. In DICTIOUS you will not only get to know all the dictionary meanings for the word User:Egbingíga, but we will also tell you about its etymology, its characteristics and you will know how to say User:Egbingíga in singular and plural. Everything you need to know about the word User:Egbingíga you have here. The definition of the word User:Egbingíga will help you to be more precise and correct when speaking or writing your texts. Knowing the definition ofUser:Egbingíga, as well as those of other words, enriches your vocabulary and provides you with more and better linguistic resources.
My name is Ayọ̀ (he/him) and I love languages! From Tahitian to Ge'ez to Gungbe, I love them all in their beauty and complexity. My primary focus here are West African languages, in addition to the occasional additions to entries for other languages once in a while.
Orúkọ mi ni Ayọ̀ (ó/òun/rẹ̀), olólùfẹ́ èdè ni mi òòò! Láti èdè Tahiti sí èdè Ge'ez tí wọ́n ti sọ ní Ìtíópíà láyé àtijọ́ sí èdè Ègùn, èdè gbogbo yìí ni mo fẹ́ràn tọkàntọkàn pẹ̀lú ẹwà àti gbogbo ìṣòro ti wọn. Ohun tí mo fọkàn mi sí i jù àwọn ohun mìíràn lọ lórí ẹ̀rọ Wiktionary yìí jẹ́ àwọn èdè láti Ìwọ̀-oòrùn Ilẹ̀ Adúláwọ̀, mo sì fẹ́ràn láti ṣe nǹkan pẹ̀lú àwọn èdè mìíràn nígbà míì.
Focus - Pàtàkì
The promotion and upliftment of the the Yoruba language online - Ìgbéga àti ìgbélárugẹ èdè Yorùbá lórí ẹ̀rọ ayélujára
The recognition of the variety which exists with the continuum of languages and varieties of Yoruba - Ìdánimọ̀ gbogbo àwọn èdè mìíràn tó wà lábẹ́ orúkọ Yorùbá, àgàgà ìyàtọ̀ ti wọn sí èdè Yorùbá àjùmọ̀lò
The addition of terms for Gungbè with the correct spelling in both the Nigerian and Beninois orthographies, with proper tone usage - Àfikún ọ̀rọ̀ fún èdè Ègùn ní ìlànà ìkọ̀wé tó tọ́, pẹ̀lú àmì ohùn tó sì pé
Numbers in Gungbe - Òǹkà lédè Ègùn
Correction of entries with tones in the page title - Àtúnṣe àwọn ìgbéwọlé pẹ̀lú àmì ohùn lórí
Addition of cognate terms - Àfikún ọ̀rọ̀ láti ẹbí èdè Gbè
The valorization of the Ìjẹ̀bú language through the documenting of language yet to be widely written - Ùgbénárugẹ eréùn Ìjẹ̀bú pẹ̀lú ùkọlẹ̀ eréùn kọ̀n rìí ònìyọn éè kọ núgbà dede nọ́jọ́ rìí a wà wèé
The addition of terms in Itsekiri and other SEY varieties - Ẹ̀fukún ọ̀rọ̀ ní eréùn Ìṣẹkírì àti nọ́wọn eréùn SEY èmúrẹ̀n - Àfikún ọfọ̀ ní èdè Ìṣẹkírì àti nághan èdè SEY múrẹ̀n